Intro: Ojuse BAO Ojuse BAO
Ajose temitire nio
Ojuse BAO.
Chor: Ojuse BAO Ojuse BAO
Ajose temitire nio
Ojuse BAO.
Solo 1: Ojuse Biodun Oyebanji
Ojuse Olori todara, (kagbepinle ekiti wa laruge)
Iranlowo araalu,
Eto aralu
Eto araalu. (Ojuse olori tomato tomato oo)
Chor: Ojuse BAO Ojuse BAO (Solo again: Ountoju arugbo ountoju odo)
Ajose temitire nio
Ojuse BAO.
Solo 2 : Iranlowo araalu,
Iyen lojuse BAO, ( Oko Olayemi )
Iranlowo ilera eda (BAO) , Asia lelelelele
Iranlowo Onisowo gbogbo, Iyen Lojuse BAO, (Biodun Ose Abayomi Ose)
Ajose temitire nioo
Ojuse BAO ( Agbajowo lafin soya laye.)
Chor: Ojuse BAO Ojuse BAO ( Solo again: kadupe lowo ori nipinle ekiti)
Ajose temitire nio (kajogbimopo kajose)
Ojuse BAO.
Solo 3: Ojuse Olori todara, eto araalu, iyen lojuse BAO
Oselu tio metanu lowo, Biodun Eleyinju aanu, Ojuse BAO.
Ayo tide, idunu de, ibukun de, ireti de
Chor: Ojuse BAO Ojuse BAO ( Karanrawa lowo, karanlu wa lowo gbogbo patapata)
Ajose temitire nio ( Faseyori kowa)
Ojuse BAO.
Solo 4: Karanrawa lowo, Ojuse Biodun Abayomi
Kade tun ranlu lowo, Kajose Kajoje,
Ajose temitire Ojuse BAO.
Chor: Ojuse BAO Ojuse BAO
Ajose temitire nio
Ojuse BAO.
Interlude: Igbagbomi duro lori …… (Keyboard)
Biodun oa leyin re ooo (Chorus Oa leyin re ooo)
Oyebanji oa leyin re o…..
Abayomi oa leyin ……
Oyebanji
Ao luko leyin re oo
Onise owo ileyin reo
Awako
Eye loja..
Aabalaje…
Akeko….
Odo…
Olomowe…
Lobaloba ….
Kete iraulu ……
Chor: Ojuse BAO Ojuse BAO
Ajose temitire nio
Ojuse BAO.